Skip to content

We use essential cookies to sign you in and remember your settings. With your permission we also use analytics cookies to understand how the site is used. See our privacy policy or fine-tune this anytime at cookie settings.

SubjectPaid lesson

EYA AWE GBOLOHUN.

ClassNotes Team 13 MIN READUPDATED 17 JUN 2026

OSE KESAN-AN

EYA AWE GBOLOHUN                       

 

Gege bi a se so saaju pe awe gbolohun pin si meji: olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe.

1            OLORI AWE GBOLOHUN Olori awe gbolohun ni gbolohun to le da duro pelu itumo.Fun apeere.

          Bola jeun ni ori tabili

          Sade ra aso ti ko ni iho lara

          Ojo gbodo jeun ki o to lo oogun re. Gbogbo awon ti a fala si nidi yii ni a pe ni olori awe gbolohun. Sade ra aso, Bola jeun, Ojo gbodo jeun; awon wonyi ni itumo ju ni ori tabili,ti ko ni iho lara,ki o to lo oogun.

2.       AWE GBOLOHUN AFARAHE

Eyi ni apa keji odidi gbolohun ti ko le da…