Loading...

EDE YORUBA SSS2 SECOND TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

OSE KIN-IN-NIAROKO ONILETAAKOONU Orisii leta meji lo wa ninu ede Yoruba, awon naa ni: Leta Gbefe ati Leta Aigbagbefe.Leta mejeeji ni o ni eto ati ilana ti a n gba ko won.Leta gbefe ni leta ti a ko si obi, ara, ore, ebi, egbon, aburo tabi si eni ti a mo ri.
OSE KEJIAayan OgbufoAKOONUAayan ogbufo ni ise titumo ede kan si ede miiran. Ki ogbufo to le kogo ja ninu itumo ede, o gbodo mo tifun tedo ede Geesi , ki o si le tusu ede Yoruba naa de isale ikoko.Kii se gbogbo oro inu ede kan naa le tumo si ode miiran.A ko gbodo mu gbolohun ni okookan lati tumo, sise bee yoo so ewa ati itumo iru ayoka bee nu.A ko gbodo mu oro ni eyo kookan lati tumo, ti a ba se bee yoo so itumo oro ti a fe tu nu.Akaye ati akatunka ayoka se pataki ki o to le se ogbufo to peye. Rii pe o lo akoto to muna doko eyi ni yoo je ki o see ka.Lilo itumo erefee ko bojumu, eyi ko ni fun wa ni itumo ti o kun, itumo ijinle ni o ye ogbufo.O san ki ogbufo lo oruko ti o wa ninu ayoka.
OSE KETALETA AIGBAGBEFE:Eyi ni leta ti a n ko si ile-ise ijoba bii ile-ise amohun-maworan, ile-ise itewe, Yunifasiti abbl. Ninu leta aigbagbefe eni ti o di ipo kan mu ni a maa n ko leta si ki i se enikan ni pato. Ko si pe a n ki ni, sere tabi se awada ninu leta aigbefe. Ibi koko leta ni a maa n lo taara. Adiresi meji ni o maa n wa ninu leta aigbagbefe. (adiresi eni ti o ko leta ati eni ti a n ko leta si). A maa n mo ipo eni ti a n ko si. Apeere: Alaga, Akowe, Oga Agba. Ori-oro tabi akole maa n wa ninu leta aigbagbefe. Inu leta/koko ti a fe bo gan-an ni a gbodo lo taara. Ipari leta. ‘Emi ni tiyin’ ni a gbodo fi pari. Oruko eni ti o ko leta. Apeere
OSE KERIINIPAROJE ATI ISUNKIAKOONUIparoje: Ni fifo awon iro tabi siso awon iro nu nigba ti a ba n yara soro. Ti a ba n yara soro, a maa n pa awon iro kan je, awon iro ti a maa n paje ni: Iro konsonanti. Faweli ati ohun. Apapo konsonanti, fawli ati ohun ninu oro.Nibi ti a ba ti pa iro je, alafo yoo wa nibe, a o wa pa iro mejeeji po di eyokan. Pipapo apa oro eyo kan ni a mo si isunki. Se ise = S( ) ise = sise (faweli ‘e’ ni a paje)Adiye = adi ( ) e adie (kons ‘y’ ni a paje)IPAJE KONSONANTIOpolopo iro Konsonanti ede Yoruba ni a le paje ninu afo/oro siso. Eyi ni awon eyo oro ti a ti pa konsonanti je ni ikookan ati ayorisi ipaje
OSE KARUN-UNARANMOAranmo ni agbara ti iro kan ni lori miiran eyi ti o le f ape ki iro mejeeji yipada di iru kan naa tabi ki won fi abuda jo ara. Apeere: Ara ile ----à araaleOmo ise ---à omoose.Oni owo --à olowo.Iro Afaramo: iro afaranmo ni iro ti o ni agbara lati yi abuda iro tabi die lara abuda iro miiran pada si tire. Apeere:Owo ile ----à owoole.Ise ilu -----à iseelu.Iro Agbaranmo: iro agbaranmo ni iro ti o yi pada gba abuda iro miiran. Apeere.Ile iwe ----à ileeweAra ile ----à araale.
OSE KEFAOro – AgbasoAkoonu Oro agbaso naa ni a mo si afo agbaran.Oro agbaso:- je siso oro ti a gbo lenu oloro fun elomiran. Iru oro tabi iroyin bee gbodo je eyi to ti koja. Oro agbaso le je ohun ti enikan so nipa wa tabi elomiran. O si le je iroyin ohun to sele nibi kan. Awon wunren atoka oro agbaso ni so, wi, ni, ki, pase, wi pe, salaye, so fun abblTunde ni oun ko ni wa si ipadeSola beere boya a ti jeunBi a ba n se agbaso, ayipada maa n de ba oro aropo oruko tabi oro aropo afarajoruko, ti eni to n soro ba lo oro aropo-oruko tabi oro aropo-afarajoruko enikinni ninu oro re – oro aropo –oruko tabi afarajoruko eniketa ni eni to n se agbaso yoo lo. Apeere:Mo ri owo he.Agbaso- O ni oun ri owo he.
OSE KEJEORO ATI GOLOHUN ONIPONNA Gbolohun oniponna-; ni gbolohun ti o ni ju itumo kan lo.gbolohun oniponna le je eyo oro tabi apola kan ni o maa ni ponna.Itupale eyo oro oniponna ninu gbolohun. Ayo ko le da mi. o tumo si pe . Ayo ko le da mi [ se eda mi ]. Ayo ko le Segun mi. Isu rira ni Badejo gbin.Tumo si- isu ti o ti ra[baje] ni Badejo gbin. Isu ti o ra ni oja ni o gbin. Ogun ile ni Ariyibi gbonju ba.tumo si pe-; ile ogun ni Ariyiibi gbonju ba[20],o tun le tumo siogun ile ti oloogbe fi sile ni Ariyibi gbonju ba.Itupale apola oniponna ninu gbolohun.Gbolohun ItumoAyo wu mi Mo feran Ayo Mo fe idunnuOmo Akin Omo ti Akin bi.
OSE KESAN-ANEYA AWE GBOLOHUN Gege bi a se so saaju pe awe gbolohun pin si meji: olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe.1 OLORI AWE GBOLOHUN Olori awe gbolohun ni gbolohun to le da duro pelu itumo.Fun apeere. Bola jeun ni ori tabili Sade ra aso ti ko ni iho lara Ojo gbodo jeun ki o to lo oogun re. Gbogbo awon ti a fala si nidi yii ni a pe ni olori awe gbolohun. Sade ra aso, Bola jeun, Ojo gbodo jeun; awon wonyi ni itumo ju ni ori tabili,ti ko ni iho lara,ki o to lo oogun.2. AWE GBOLOHUN AFARAHEEyi ni apa keji odidi gbolohun ti ko le da duro funra re,o fi ara he olori awe gbolohun ni Apeere: -
OSE KEWAAAPOLAAKOONU: - Ki ni a n pe ni Apola. Ki ni Apola oro Oruko Ise ti Apola Oro Oruko n se ninu Gbolohun? Ki ni a n pe ni Apola ise? Ise ti Apola Ise n se ninu GbolohunApola ni akojopo oro ti o n di apa kan gbolohun. Apola le je eyo oro kan, o si le je meji tabi ju bee lo. Orisiri apola lo maa n di apa kan tabi odidi gbolohun.Apola oro oruko ni eyo oro oruko kan tabi meji tabi ju bee lo ti o di apa kan odindi. O si le je apapo oro oruko ati oro oruko eyan ninu gbolohun Yoruba. Apola oro oruko le je oro oruko, oro aropo oruko, tabi aropo afara joruko.Apeere apola to je eyo oro oruko kanIweMotoAsoIlekeApola le je eyo oro oruko meji tabi ju bee loOju titiOmi ojoBaba agbeIgi okoAwa omo baba olowo ilu yii niyi. Oko ayokele oloye ni mo raApola oro oruko ati eyan

Subject Reviews:

Average Rating0
  0 Ratings
  Details
  5 Stars0%0
  4 Stars0%0
  3 Stars0%0
  2 Stars0%0
  1 Stars0%0

  No reviews yet.

  Also available in Bundles