EYA ARA IFO. : LSUS

OSE KEJE

EYA ARA IFO

Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke erigi isale, eyin ahon, iwaju ahon, eyin ahon.

 

EYA ARA IFO

  1. EYA ARA IFO TI A LE FOJU RI: awon eya ara wonyi ni a le fi oju ri. Apeere: iho imu, kaa imu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo-fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke, erigi isale iwaju ahon, aarin ahon ati eyin ahon, afase, olele, aja enu, ita gogongo, kaa imu.
  2. EYA ARA IFO TI A KO LE FI OJU RI: eya ara ifo ti won wa lati inu ikun si inu ofun ti a ko le fi oju ri. Awon ni: kaa ofun, inu gogongo, tan-an-na, komookun, eka komookun, edo-foro, eran edo-fooro, efonha.

 

AFIPE

View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.