Loading...

EDE YORUBA SSS2 THIRD TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

OSE KIN-IN-NIAROKO AJEMO ISIPAYAAroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Apeere aroko ajemo-isipaya ni: Ise Tisa Oge Seise. Aso Ebi Imototo. Ise ti mo fe lojo iwaju.Ki a to le ko akoyawo lori okookan ori-oro wonyi, a gbodo ni arojnle ohun ti won je, itumo ati itumo won miiran to farasin tabi ohun ti o ni abuda won. A nila ti wo anfaani ati aleebu ki a si fi arojinle ero gbe won kale.
OSE KEJIORI-ORO-;SILEBU EDE YORUBA Oriki. Ihun silebu. AKOONU:- Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan sosoIye ohun ti o ba wa ninu oro ni iya silebu ti oro naa yoo ni.Fun ApeereWa-je oro onisilebu kan nitori pe ami ohun kan ni o wa lori re. I / we = 2 Ba / ta = 2 Ihun silebu:- Ona meta Pataki ni ihun silebu pin si awon naa ni:- Ihun faweli kansoso Ihun to je konsonanti ati faweeli.
OSE KETAAYOKA ONISOROGBESIKa ayoka isale yii,ki o si dahun ibeere ti o tele e Ayo; O da a,aanu re lo se mi O mo on so, o dun lete re bi oyin N o gba o si egbe wa.Baba Ramo Haa! E seun o. Mo dupe o.Ayo Sugbon owo iwegbe re n ko- Poun meedogunBaba Ramo Howu! Mo te patapata nu-un Onini sagba mi lonii…….. sugbon mo be yin e gba mi.Ayo Oro re ti e tu mi lara.
OSE KERINISEDA ORO-ORUKOAKOONU Oriki Orisii Ona ti a n gba Seda Oro-Oruko Iseda Oro-Oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi a ba fe seda oro oruko, eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.1. Nipa lilo Afomo Ibere Nipa lilo Afomo Aarin Nipa sise Apetunpe kikun Nipa sise Apetunpe Elebe Nipa sise Akanpo Oro-Oruko Nipa sise Isunki odidi Gbolohun.
OSE KARUN-UNONKA (2,000-50,000).Onka Geesi
OSE KEFAORUNMILAOrunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo odun ni Ife Ondaye ki o to lo si Ado. Ibi ti o tip e julo ni ode aye. Idi niyi ti won fi n so pe ‘Ado n’ile Ifa’ Orunmila tun gbe ni Otu Ife. Ibe ni o ti bi awon omo wonyi: Alara, Ajero, Owarangun-aga, Oloyemoyin, Ontagi-Olele, Elejelu-mope ati Olowo. O tun gbe ni Ode Oyan. Ibi ti o ti bi Amukanlode-Oyan. Bakan naa ni o gbe ni ode Onko ti o ti bi Amosunlonkoegi.
OSE KEJEEYA ARA IFOEya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke erigi isale, eyin ahon, iwaju ahon, eyin ahon.
OSE KEJOIRO FAWELIIro-Ede -; ni ege ti o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede, ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa yoo maa gbo.A le ko iro –ede sile nipa lilo leta tabi ami.Iro-ede ti a ni pin si ona meta; Iro faweli Iro konsonanti Iro ohun.Iro Faweli:- ni iro ti a pe nigba ti ko si idiwo fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.Ona meji ni iro faweli pin siFaweli Airanmupe.Faweli Aranmupe.
OSE KESAN-ANIRO KONSONANTIIro konsonanti-; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba. Awon naa ni; b,d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, s, t, w, y.
OSE KEWAAAMI OHUN Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m ati n’’ Ninu ede Yoruba, oro eyokan pelu sipeli kanna le ni opolopo itumo paapaa julo ni iwon igba ti oro yii ba ti ni ami otooto lori. Ami ori oro meta ni a o gbe yewo ninu iwe yii. Awon naa ni: Ami o oke, ami isale ati ami aarin. Ami ohun oke ( / ) mi.Ami ohun isale ( \ ) do. Ami ohun aarin( - ) re.

Subject Reviews:

Average Rating0
    0 Ratings
    Details
    5 Stars0%0
    4 Stars0%0
    3 Stars0%0
    2 Stars0%0
    1 Stars0%0

    No reviews yet.

    Also available in Bundles