ORI-ORO ; APEJUWE IRO KONSONANTI : LSUS
OSE KERIN
ORI-ORO ; APEJUWE IRO KONSONANTI
AKOONU
Iro konsonanti; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o ti inu edofooro bo.Iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba awon naa ni b,d,f,g,gb,h,j,k,l,m,n,p,r,s,s,t,w.y.
ABUDA FUN ISAPEJUWE IRO KONSONANTI
Eyi ni awon abuda ti a maa tele ti a ba fe sapejuwe iro konsonanti
Ipo ti alafo tan-an-na wa
Ipo ti afase wa.
Ibi isenupe
Ona isenupe.
IPO TI ALAFO TAN-AN-NA WA
Bi a ba tele abuda yii,ona meji ni a le pin iro konsonanti si
Konsonantiaikunyun
Konsonanti akunyun
Konsonanti aikunyun-;ni iro ti ti a pe nigba ti alafo tan-an-na fi aye ti o to sile fun eemi ti o n ti inu.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.