ORI-ORO ILANA ATI OGBON TI A N TA FUN AROKO KIKO : LSUS
OSE KEJO
ORI-ORO ILANA ATI OGBON TI A N TA FUN AROKO KIKO
AKOONU
Itumo,
Orisiirisii Aroko
Aroko je ona ti a fi n mu eniyan ronu lori koko oro kan,ki o si ko ero re sile laifi atamo-mo-atamo..
ORISIIRISII AROKO.
Orisiirisii Aroko ni o wa ninu ede Yoruba,awon naa ni : -
Aroko oniroyin / asotan.
Aroko alapejuwe
Aroko onisorongbesi
Aroko ajemo-isipaya
Aroko alarinyanjiyan
Aroko leta kiko.
EROJA PATAKI FUN AROKO KIKO.
Eyi ni awon ohun ti o gbodo je akekoo logun,ti yoo fii je ki o le gbe aroko ti o gbamuse kale.
- Yiyan ori oro: - Akekoo gbodo yan.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.