Loading...

EDE YORUBA SSS1 FIRST TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

OSE KINNIORI-ORO : Awon Eya Ara Ifo -Eyi ti a le fojuri ati eyi ti a ko le fojuri-Afipe asunsi ati akanmole. AkoonuEya ara ifo-;eyi ni awon eya arati won n sise papo lati gbeiro-ede jade.Eya ara ifo-;eyi ni gbogbo awon eya ara ti o kopa nigba ti a ba n soro.Apeere awon eya ara ifo ni;Ahon, ete, afase, eyin, erigi,komookun,tan-an-na,olele,aja-enu,gogongo,alafo tan-an-na abbl.
OSE KEJIORI-ORO-; IRO-EDE ORIKI IRO-EDE -ORISII IRO-EDEAKOONUIro-ede -; ni ege ti o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede,ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa yoo maa gbo.A le ko iro –ede sile nipa lilo leta tabi ami.Iro-ede ti a ni pin si ona meta; Iro faweli Iro konsonanti Iro ohun.
OSE KETAORI-ORO- APEJUWE IRO FAWELI ORIKI,ABUDA IDAKO ATE FAWELIAKOONUIro faweli-;ni iro ti a pe nigba ti ko si idiwo fun eemi ti o n ti inu edofooro bo. ORISIIOna meji ni iro faweli pin si Faweli airanmupe Faweli aranmupe
OSE KERINORI-ORO ; APEJUWE IRO KONSONANTIAKOONUIro konsonanti; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o ti inu edofooro bo.Iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba awon naa ni b,d,f,g,gb,h,j,k,l,m,n,p,r,s,s,t,w.y.ABUDA FUN ISAPEJUWE IRO KONSONANTIEyi ni awon abuda ti a maa tele ti a ba fe sapejuwe iro konsonanti Ipo ti alafo tan-an-na wa Ipo ti afase wa. Ibi isenupe Ona isenupe.
OSE KAARUNORI-ORO IRO- OHUN ORIKI ORISIIAKOONU Iro-ohun-; ni lilo soke,lilo sodo tabi yiyo roketabi rodo ohun wa nigb ti ba n soro. Ona meji ni iro ohun pin si Iro-ohun geere Iro –ohun eleyoo.IRO-OHUN GEERE- eyi ni ki iro-ohun eniyan duro si ipo kannaa laini eyo rara.Iro-ohunlo je ka mo iyato oro kan ti won ni sipeli kan naa yato si ikeji.Ona meta ni iro-ohun geere pin si Iro-ohun oke
OSE KEFAORI ORO-SILEBU NINU EDE YORUBA -ORIKI -IHUN -BATANI -ODO ATI APALA SILEBU AKOONU Odo silebu;ni apa to gbe se pataki julo ninu ihun silebu kookan.Iro faweli ati iro konsonanti aranmupe asesilebu ni o maa n sise gege bi odo silebu.Awon iro odo silebu ni a maa n gbo ju ninu oro.Ori odo silebu ni a maa n fi ami ohun siKan-an-n-pa ni odo silebu je ninu ihun silebu.Ap
OSE KEJEORI-ORO AKOTO EDE YORUBA ITAN BI EDE YORUBA SE DI KIKO SILEAKOONUKi owo eru to bere ni iwo oorun Afirika,asa iwe kika sajeji ni ile Yoruba,a kan n so ede Yoruba lenu lasan ni,ko si akosile.Nigba ti owo eru bere opolopo omo Yoruba ni awon onisowo alawo funfun ko leru lo si ilu won.Leyin opolopo odun ni won fi opin si owo eru yii gbogbo awon ti won ko leru ni won so di ominira ni ile saro(Freetown) ti won si bere igbe aye titun.Leyin opin owo eru yii ajosepo si n tesiwaju laarin iwo oorun pelu awon alawo funfun ,won wa ra ohun elo fun ile-ise okowo won.Laarin akokoyii, awon alawo funfun gbagbo pe eniyan dudu ko ni esin pe abogibope ni won, idi niyi ti won fi mu esin kristieni wa fun wa,ti esin titun yoo ba si fese mule,odi dandan ki awon ajhinrere to mu esin wa gbe ni aarin awon eniyan ti won n waasu fun.
OSE KEJOORI-ORO ILANA ATI OGBON TI A N TA FUN AROKO KIKOAKOONU Itumo,Orisiirisii Aroko Aroko je ona ti a fi n mu eniyan ronu lori koko oro kan,ki o si ko ero re sile laifi atamo-mo-atamo.. ORISIIRISII AROKO.Orisiirisii Aroko ni o wa ninu ede Yoruba,awon naa ni : - Aroko oniroyin / asotan. Aroko alapejuwe Aroko onisorongbesi Aroko ajemo-isipaya
OSE KESAN- ANORI-ORO -;AKANLO EDE -ORIKI -IWULO AKANLO EDE - AKANLO EDE ATI ITUMO WON AkoonuAkanlo ede je ipede ti o kun fun ijinle oro eyi ti itumo re farasin pupo.Isoro ni soki ni akanlo ede wa fun.O si tun wulo pupo nigba ti a ba fe pe oro so, ti a ko fe ki gbogbo eniyan gbo nnkan ti a n soAkanlo ede le je eyo oro kan pere apola tabi ki o je odidi gbolohunapAKANLO-EDE ITUMOo fori gbota o se konge aburuo tele nibi ile gbe loju o si rin o faraya o binu gan anna papa bora salopa ni apafon pa ku patapata
OSE KEWAAORI –ORO -;LILO AKANLO-EDE NI GBOLOHUNAKOONU Eyi ni lilo akanlo-ede ti a ti gbe yewo ni gbolohun lati fi itumo won han.Gomina Raji Fasola se gudugudu meje yaaya mefa ni ipinle Eko.Gbogbo ise ti Alaaja n se lati odun yii wa, ajadi apere lo n pa owo si.Nigba ti okunrin naa da wahala sile tan ni o ba fie se fee.Iya ibeji tuto soke osi fi oju gba a nigba ti o gbo pe omo re feraku.Omi ti Sola bu fun baba agba ti sewon.

Subject Reviews:

Average Rating0
    0 Ratings
    Details
    5 Stars0%0
    4 Stars0%0
    3 Stars0%0
    2 Stars0%0
    1 Stars0%0

    No reviews yet.

    Also available in Bundles