ARANMO : LSUS
OSE KARUN-UN
ARANMO
Aranmo ni agbara ti iro kan ni lori miiran eyi ti o le f ape ki iro mejeeji yipada di iru kan naa tabi ki won fi abuda jo ara. Apeere:
Ara ile ----à araale
Omo ise ---à omoose.
Oni owo --à olowo.
Iro Afaramo: iro afaranmo ni iro ti o ni agbara lati yi abuda iro tabi die lara abuda iro miiran pada si tire. Apeere:
Owo ile ----à owoole.
Ise ilu -----à iseelu.
Iro Agbaranmo: iro agbaranmo ni iro ti o yi pada gba abuda iro miiran. Apeere.
Ile iwe ----à ileewe
Ara ile ----à araale.
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.