EYA AWE GBOLOHUN. : LSUS
OSE KESAN-AN
EYA AWE GBOLOHUN
Gege bi a se so saaju pe awe gbolohun pin si meji: olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe.
1 OLORI AWE GBOLOHUN Olori awe gbolohun ni gbolohun to le da duro pelu itumo.Fun apeere.
Bola jeun ni ori tabili
Sade ra aso ti ko ni iho lara
Ojo gbodo jeun ki o to lo oogun re. Gbogbo awon ti a fala si nidi yii ni a pe ni olori awe gbolohun. Sade ra aso, Bola jeun, Ojo gbodo jeun; awon wonyi ni itumo ju ni ori tabili,ti ko ni iho lara,ki o to lo oogun.
2. AWE GBOLOHUN AFARAHE
Eyi ni apa keji odidi gbolohun ti ko le da duro funra re,o fi ara he olori awe gbolohun ni Apeere: -
Ode wa mu oti yo ni oru ana
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.