IPAROJE ATI ISUNKI : LSUS

OSE KERIIN

IPAROJE ATI ISUNKI

AKOONU

Iparoje:  Ni fifo awon iro tabi siso awon iro nu nigba ti a ba n yara soro. Ti a ba n yara soro, a maa n pa awon iro kan je, awon iro ti a maa n paje ni:

  • Iro konsonanti.
  • Faweli ati ohun.
  • Apapo konsonanti, fawli ati ohun ninu oro.

 

Nibi ti a ba ti pa iro je, alafo yoo wa nibe, a o wa pa iro mejeeji po di eyokan.  Pipapo apa oro eyo kan ni a mo si isunki.

  Se ise = S(   )  ise =  sise (faweli ‘e’ ni a paje)

 

Adiye = adi (   ) e    adie (kons ‘y’ ni a  paje)

 

IPAJE KONSONANTI

Opolopo iro Konsonanti ede.... View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.