GBOLOHUN EDE YORUBA : LSUS
OSE KEFA
GBOLOHUN EDE YORUBA
gbolohun ni ipede ti o kun pelu itumo kikun. Orisii eya gbolohun meji ni o wa. Awon eya naa ni: (i) gbolohun ni ilana ihun ati
(ii) gbolohun ni ilana ise tabi ise ti o n je.
- Gbolohun ni Ilana Ihun ni: gbolohun eleyo oro ise (abode), olopo oro ise (onibo) ati alakanpo.
- Gbolohun eleyo oro ise o maa n ni eyo oro ise kan. Apeere: ade pa eku.
- Gbolohun Olopo Oro-Ise: o maa n ni ju eyo oro ise kan lo. Apeere: Kunle sare tete lo pon omi
- Gbolohun alakanpo: o maa n gbolohun meji ninu. O si maa ni oro asopo ninu pelu. Apeere: Apeere: Olu je buredi ati eyin.
- Gbolohun ni Ilana Ise/ise ti o n je: apeere gbolohun alalaye, ase, ibeere, kani, ayisodi,
- View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.