ONKA (101-200) : LSUS
OSE KEJE
ONKA (101-200)
Opolopo eniyan ni o ro wi pe awon alawo funfun ni o ko awon Yoruba ni onka. Ko ri be rara. Ki awon alawo funfun to de ni awon Yoruba ti n se isiro orisiirisii nnkan. Onka lati ookan titi de igba ni a fe yewo bayi. Ona meji ni a fi n se onka ninu ede Yoruba. A le so pe eni, eji tabi ki a so pe meni (mu eni), meji (mu eji) ati bee bee lo. Idi-idi ni onka Yoruba. Eyo onka Yoruba mewaa ni o wa ninu idi kookan. Eyo mewaa akoko ni o ni oruko otooto ti a n pe won. Awon ni iwonyi:
1 - ookan okan.
2 - eeji meji.
3 - eeta meta.
4 - eerin merin.
5 - aarun maru-un.
6 - eefa .... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.