ORO-APONLE : LSUS
OSE KKARUN-UN
ORO-APONLE
Oro aponle ni a n lo lati yan tabi se afikun itumo fun oro ise tabi apola-ise ninu gbolohun.
Ise oro-aponle ni lati se afikun itumo fun apola-ise ninu gbolohun lati mu ki itumo re yeni yekeyeke si bi apeere:
Tun n rin werewere lo si ile
Ade n rin kanmokanmo bo.
Fadeke n jenu waduwadu.
Adebisi n soro fatafata ni kilaasi.
Igi osan naa ga fiofio.
IGBELEWON
Lo awon oro aponle yii ni gbolohun: jiajia, resuresu, boo, yoo, ponpon, bantu.
IWE AKATILEWA
Oyebamji Mustapha (2009) Eko Ede Yoruba Titun oju iwe 219-222 University Press Plc.
AWON IGBESE TI AGBE YOO GBE KI IRE OKO TO JADE
Igba laso, igba leeyan igba l’oderekoko lajule orun. Beeni, igba ojo,.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.