LETA GBEFE : LSUS
OSE KIN-IN-NI
LETA GBEFE
AKOONU: Itumo
Adireesi
Deeti
Ikini ibere
Koko aroko
Asokagba
Ikini ipari
Leta kiko ni ona ti a n gba ranse asiri si ara eni. Oun ni o duro fun aroko pipa lode oni. A maa n fi ero ara eni han ninu iru leta (aroko) yii. Aroko onileta nise pelu kiko sile. Leta yii pin si orisii meji awon naa ni: leta gbefe ati leta aigbefe. Leta gbefe ni leta si obi, ore, ibatan ati awon miiran ti o sun moni.
Igbese/Ilana Leta Gbefe
Kiko adireesi: oke apa otun ni a maa n ko adireesi eni ti o n ko leta si. Ninu adireesi yii, a maa n ri nomba, adugbo,opopona, ipinle. Fun apeere:
.... View MoreSubscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.