APOLA ORUKO (Phrases) : LSUS
OSE KEJI
APOLA ORUKO (Phrases)
Apola ni apa kan gbolohun ti o le je oro tabi akojopo oro. Lara apola inu ede Yoruba ni apola oruko, aopla ise, ati apola aponle.
Apola Oruko (noun phrase): okan ninu apola oro ti a hun po di gbolohun ni apola oruko. Apola Oruko le je:
- Oro Oruko eyo kan ni ipo oluwa tabi ni ipo abo. Apeere;
Yetunde sun fonfon
Epo wa ni Sapele.
- Oro Oruko tabi Akojopo Oro Oruko ti o n sise eyan. Apeere:
Omi kanga maa n lo ni enu.
Ijoba Ibile Somolu ko awon iso wewe.
- Oro Oruko ati Eyan Alawe Gbolohun: apeere:
Iyabo ti a n soro re ti de.
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.