EDE LETA AIGBEFE : LSUS
OSE KEFA
EDE
LETA AIGBEFE
Akoonu:
- Leta aigbefe
- Igbese kiko leta aigbefe
Leta aigbefe je leta ti ko gbefe rara, ti a n ko si eni ti o wa ni ipo tabi aaye owo. O le je leta iwase, leta ifisun, leta igbaaye lenu ise, leta si ijoba ibile. Igbese meje ni a ni lati tele bi a ba fe ko leta aigbefe. Awon naa ni:
- Kiko adireesi akoleta
- Kiko deeti ( ojo, osu ati odun ti a ko leta)
- Ipo ati adireesi eni ti a ko leta si
- Ikini ibere leta
- Akole leta
- Koko oro inu leta
- Ipari ati oruko akoleta
Kiko adireesi akoleta: bakana ni eleyi ri pelu leta.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.