EDE LETA GBEFE : LSUS
OSE KIN-IN-NI
EDE
LETA GBEFE
AKOONU: Leta
Adiresi
Deeti
Ikini ibere
Koko oro
Asokagba
Ikini ipari
Leta kiko ni ona ti a n gba ranse asiri si ara eni. Oun ni o duro fun aroko pipa ranse lode oni. A maa n fi ero ara eni han ninu iru leta (aroko) yii. Leta pin si orisii meji awon naa ni: leta gbefe ati leta aigbefe. Leta gbefe ni leta si obi,ore, ibatan ati awon miiran ti o sun moni. Ilana leta gbefe ni: adiresi, deeti, ikini ibere, koko aroko, ikini ipari.
Kiko adireesi: oke apa otun ni a maa n ko adiresi eni ti o n ko leta si. Adiresi yii maa n ni awon nnkan wonyi ninu: nomba, adugbo,opopona, ipinle. Fun apeere:
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.