EDE APOLA APONLE : LSUS
OSE KESA-AN
EDE
APOLA APONLE
Oro aponle ni awon oro tabi akojopo oro to n sise aponle fun oro ise. Apeere oro aponle ni daradara, kiakia, foo. Orisiirisii oro aponle ti ani ninu ede Yoruba ni: apola aponle oniba, apola aponle alasiko, apola aponle onibi, apola aponle onidii, apola aponle alafiwe.
Apola Aponle Oniba: Apola aponle yii maa n toka si isesi, iba tabi bi a se n se nnkan ninu gbolohun. A le lo wuren ibeere *Bawo ni* fun irufe awon gbolohun wonnyi. Fun apeere:
Pupa foo
Tutu nini
Ga fiofio
Ara baba naa ya diedie
Igi agala naa ga fiofio.
Apola Aponle Alasiko: Gege bi oruko re se ri ni. Awon wonyi ni i se pelu asiko (time). Wuren ibeere ti o wulo fun eleyi julo ni.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.