AKORI ISE: - Eya awe gbolohun Yoruba : LSUS

OSE KEJO

AKORI ISE: - Eya awe gbolohun Yoruba                                                           

AKOONU: -

    • Olori awe gbolohun
    • Awe gbolohun afara he 

 

Gbolohun Yoruba to kun maa n ni itumo kan, o si maa n ni ise kan pato to n je. Ohun ti a mo si awe gbolohun ni tire je apa kan odidi gbolohun. Ara odidi gbolohun ni a ti fa awe gbolohun yo. Orisi awe gbolohun meji Pataki ni a le fa yo ninu ihun gbolohun . Yoruba awon olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe.

1.       OLORI AWE GBOLOHUN

          Oun ni abala gbolohun to le da duro funra re ki o si in itumo ti a ba yo afi kun re kuro. Apeere.

          Mo ti lo ki ore mi to de

Gbogbo ilu gbo View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.