IBASEPO LAARIN AWE GBOLOHUN ATI ODINDI GBOLOHUN : LSUS

OSE  KEJE                                         

IBASEPO LAARIN AWE GBOLOHUN ATI ODINDI GBOLOHUN

Gbolohun ni ipede ti o kun pelu ituno nigba ti awe gbolohun je apa kan odindi gbolhun Ara odindi gbolhun ni a ti fa awe gbolohun yo. Awe gbolohun pin si ona meji. Olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe

Gbolohun ni ipede ti o kun ti o si loorin. Ero ati itumo gbolohun maa n kun Fun apeere

          Mo gbo pe o ti wa mi wale

Apa kan odindi gbolohun ni awe gbolohun. Fun apeere:

          Mo gbo  pe o ti wa mi wale  Eyi ti a fala si nidi ni a pe ni awe gbolohun afarahe. Nitori naa a maa n fa awe gbolohun yo ninu odindi gbolohun.

Nigba miiran, awe gbolohun le da duro  bi odindi gbolohn. Ti o ba ri bayi olori awe gbolhun ni a n toka si. Fun apeere.

Mo sa lenu ise nitori pe o re mi

View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.