GBOLOHUN IBEERE : LSUS
OSE KARUN-UN
GBOLOHUN IBEERE:- Gbolohun ibeere ni gbolohun ti a fi maa n se iwadi nnkan. Wuren gbolohun ibeere ni: da, nko, n je, ta, tai ni, Bawo, se, ki Apeere.
Ki ni oruko re?
Iwe yen da?
Nje e ti gbo?
Ta ni o n bo? Ta ni o kan ilekun?
Bawo ni ara re?
Se o ti jeun?
IGBELEWON:
- Ko marun sile ninu wuren ibeere
- Lo awon wuren ibeere naa ni gbolohun.
IWE AKATILEWA
Eko ede ati asa Yoruba. iwe keta oju iwe 18 – 21 lati owo egbe akomolede ati asa Yoruba.
AKORI ISE (ASA): ASA IRANRA – ENI – LOWO.
Asa iranra – eni – lowo ni ona ti awon yoruba maa.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.