APOLA. : LSUS

OSE KETA

APOLA

AKOONU: -                                                             

    • Ki ni a n pe ni apola
    • Ki ni apola oro oruko
    • Ise ti apola oro oruko n se ninu gbolohun
    • Ki ni a n pe ni apola ise
    • Ise ti apola ise n se ninu gbolohun

Apola ni akojopo oro ti o n  di apa kan gbolohun. Apola le je eyo oro kan, o si le je meji tabi ju bee lo. Orisiri apola lo maa n di apa kan tabi odidi gbolohun.

Apola oro oruko ni eyo oro oruko kan tabi meji tabi  ju bee lo ti o di apa kan odindi. O si le je apapo oro oruko ati oro oruko eyan ninu gbolohun Yoruba. Apola oro oruko le je oro oruko, oro aropo oruko, tabi aropo afara joruko.

Apeere apola to je eyo oro oruko kan

.... View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.