HIHUN ORIISIRISSI AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN : LSUS
OSE KIN-IN-NI
HIHUN ORIISIRISSI AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN
AKOON: ODIDI GBOLOHUN
AWE GBOLOHUN
Gbolohun ni iso ti o kun lati ero okan eni wa TABI ki a so wi pe Gbolohun ni ipede ti o kun pelu itumo ti o si ni ise ti o n se. Bi a ba fe ba enikan soro tabi ti a ba fe se iroyin, a maa n se amulo orisii eya gbolohun bi: gbolohun eleyo oro ise, olopo oro ise,alakanpo, ibeere abbl. Ki a ranti pe ninu gbolohun kan, oro ise se pataki nibe. Fun apeere ( odidi gbolohun).
Wa.
Ade sun si ori aga.
Mo wa nile.
Kunle je eba ni ana.
Ti a ba wo awon gbolohun oke yii.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.