Loading...

EDE YORUBA JSS3 SECOND TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

OSE KIN-IN-NIHIHUN ORIISIRISSI AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN AKOON: ODIDI GBOLOHUN AWE GBOLOHUNGbolohun ni iso ti o kun lati ero okan eni wa TABI ki a so wi pe Gbolohun ni ipede ti o kun pelu itumo ti o si ni ise ti o n se. Bi a ba fe ba enikan soro tabi ti a ba fe se iroyin, a maa n se amulo orisii eya gbolohun bi: gbolohun eleyo oro ise, olopo oro ise,alakanpo, ibeere abbl. Ki a ranti pe ninu gbolohun kan, oro ise se pataki nibe. Fun apeere ( odidi gbolohun).
OSE KEJIAROKO LETA AIGBEFELeta kiko je ona kan pataki ti a n lo lati ranse si ara eni. Kiko ni a maa n ko o. Ko si ohun ti a o le ko si eniyan afi eyi ti a ko fe ko. A le pin leta kiko si orisii ona meji pataki. Akoko ni leta gbefe (informal letter) nigba ti ekeji je leta aigbefe (formal letter).
OSE KETA IYATO TO WA LAARIN APOLA ATI AWE GBOLOHUNAwe gbolohun ; - Laisi gbolohun, ko le si awe gbolohun rara. Ara gbolohun ni a ti fa awe gbolohun yo. Gbolohun eleyo oro ise a maa je olori awe gbolohun, nitori wi pe eyo oro ise kan ni o wa ninu re ti ko si gun gbooro. Sugbon ninu gbolohun olopo oro ise tabi gbolohun alakanpo ni a ti maa n ri awe gbolohun afarahe.Awe gbolohun afarahe je eyo oro tabi akojopo oro ti ko le da duro funrare laisi olori awe gbolohun. Awe gbolohun afarahe le je:-i.awe gbolohun afarahe asaponle.ii. awe gbolohun afarahe asodoruko.
OSE KERINAROKO ALALAYE AKOONU: Aroko Alalaye Ilapa eroAroko alalaye ni a fi n se ekunrere alaye lori ori-oro kan ti eni ti o ba ka aroko bee ko fi ni ni isoro lati mo ohun ti alaye wa da le lori. Apeere ori oro aroko alalaye ni : Ise ti mo fe se lojo iwaju. Igba erun. Eba tite. Ise tisa. Eran osin.
OSE KARUN-UNAROKO ALALAYE KIKO AROKO ALALAYE (APEERE)ISE TI MO FE SE LOJO IWAJUIru ise wo ni o fe se lojo iwajuAlaye lekunrere lori ise naaIdi ti ise naa fi wu oIru ipo wo ni ise yii le gbe o deEro re lori ise yii.EBA TITEIru ounje wo ni eba?Ibo ni eba yii ti wopo?Bawo ni won se n te eba ( alaye ekunrere)Ki ni o fa ti o fi feran eba?Iru ise wo ni eba n se lara.
OSE KEFAAKAYE (Ni ile akanbi, Adetutu n fo aso, Omolola, iyawo n gbale)Omosola gbale si Adetutu lara, o da aso re nu. Wahala bere. Omosola gba kuuru mo iyaale re, oni … enikan ni yoo lo fun enikeji ninu ile yii…. Omosola ni iyaale oun ni ko je ki oun loyun. Adesola fun aso mo Adetutu lorun. Adetutu kigbe pe ara ile e gba mi. Omosola de eyin mo on lapa. Adetutu ja ara re gba, o sa wole. Omosola bu serin. O ni mo fi eyin dara si lara….. Omosola n da soro ko mo pe Adetutu n gbo: “Sebi Adesewa, akobi re, emi ti mo yanju re niyi….
OSE KEJEAKAYE (EWI)IWULO IYIPADA Iyipada ki i se ohun eru Iyipada ki i se ohunn a sa fun Nse lo ye ka maa reti re Nitori bi o si iyipada,Eyin o le dakuko Agbado te e si ri n ko?
OSE KEJOATUNYEWO EYAN Eyan ni awon oro ti a n lo lati yan oro oruko. Awon oro wonyi maa n bu kun itumo oro oruko ninu gbolohun ni gege bi oro aponle ti maan fi kun itumo oro ise. Ni opo igba won maa n tele oro oruko ti won n yan. A ni eyan ajoruko, eyan asapejuwe, eyan asonka, eyan asafihan, eyan atoka asafihan. Fun apeere:1 Eyan Ajoruko:Ile oba ni a waOwo Dupe ni mo naOwo moto mi da?
OSE KESAN-ANORO APONLEOro aponle (adverb): Oro aponle ni a fi n pon oro-ise le ninu gbolohun. Ni opo igba a maa n ba won ni iwaju oro ise ninu gbolohun ni. Bi apeere: Igi ope naa ga fiofio Oko naa run womuwomu

Subject Reviews:

Average Rating0
    0 Ratings
    Details
    5 Stars0%0
    4 Stars0%0
    3 Stars0%0
    2 Stars0%0
    1 Stars0%0

    No reviews yet.

    Also available in Bundles