ORO APONLE. : LSUS
OSE KESAN-AN
ORO APONLE
Oro aponle (adverb): Oro aponle ni a fi n pon oro-ise le ninu gbolohun. Ni opo igba a maa n ba won ni iwaju oro ise ninu gbolohun ni. Bi apeere:
Igi ope naa ga fiofio
Oko naa run womuwomu
Ata naa pon wee
Olu sare tete
IGBELEWON
- fa ila si idi oro aponle ninu awon gbolohun wonyi
Omo naa fo feere
Ise yii le jojo
O n jeun waduwadu
Iwe naa ya perepere.
AKATILEWA
- Oyebamiji Mustapha (2002) Eko ede Yoruba titun Iwe keji (J.S.S.3) oju iwe 1-4 University Press Plc.
- S.Y Adewoyin (2004) New simplified Yoruba L1 iwe keta oju ewe 1-5 Copromutt (publishers) Nigeria Limited.
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.