IYATO TO WA LAARIN APOLA ATI AWE GBOLOHUN : LSUS
OSE KETA
IYATO TO WA LAARIN APOLA ATI AWE GBOLOHUN
Awe gbolohun ; - Laisi gbolohun, ko le si awe gbolohun rara. Ara gbolohun ni a ti fa awe gbolohun yo. Gbolohun eleyo oro ise a maa je olori awe gbolohun, nitori wi pe eyo oro ise kan ni o wa ninu re ti ko si gun gbooro. Sugbon ninu gbolohun olopo oro ise tabi gbolohun alakanpo ni a ti maa n ri awe gbolohun afarahe.
Awe gbolohun afarahe je eyo oro tabi akojopo oro ti ko le da duro funrare laisi olori awe gbolohun. Awe gbolohun afarahe le je:-
i.awe gbolohun afarahe asaponle.
ii. awe gbolohun afarahe asodoruko.
iii. awe gbolohun afarahe asapejuwe.
AKIYESI;-Odidi gbolohun leyin pe o gbodo ni olori awe gbolohun le ni ju awe gbolohun afarahe kan lo.
APOLA.
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.