Ori-oro-; Aroko oniroyin : LSUS
OSE KESAN-AN
Ori-oro-; Aroko oniroyin
Akoonu:
Aroko oniroyin:- je mo iroyin sise tabi itan isle ti o ti koja seyin ti o si se oju eni ti a n royin re ni sise-n-tele ninu aroko oniroyin fun elomiran ti ko si nibe. A rii wi pe o fi ara pe aroko asapejuwe.
Ki a to le se iroyin yori, a gbodo je eni ti o ni ife si gbigbo tabi kika iwe itan kekere.
Eyi ni apeere ori-or, to je mo aroko oniroyin.
Iroyin ipade maje – o – baje kan ti mo lo.
Ayeye odun eyo ni ilu eko
Ojo buruku, esu gbomi mu.
Ipolongo eto idibo ti o koja
Bi mo se lo isinmi mi ti o koja
Isomoloruko kan ti won se ni odede.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.