ORI-ORO-;SISE AYOKA EDE GEESI SI EDE YORUBA : LSUS
OSE KEFA
ORI-ORO-;SISE AYOKA EDE GEESI SI EDE YORUBA
ASA
ORI-ORO-; IGBEYAWO ODE-ONI
- IGBEYAWO SOOSI
- IGBEYAWO MOSOLASI
- IGBEYAWO KOOTU
Lode oni, aye ti di amulumala. Orisirisi ona ni a n gba gbe iyawo. A n gbe iyawo ni ile Olorun, a n gbe e ni kootu, a si n gbe ni mosalasi. Igbeyawo soosi yii fese mule laarin awon onigbagbo, igbeyawo mosalasi si mule laarin awon musulumi.
Igbeyawo soosi ni eyi to maa n waye laarin awon elesin Kristeni ninu ile ijosin won, sugbon ki eto igbeyawo yii to waye ni won yoo ti maa kede eni to ba ri idi ti won ko le fi so oko ati iyawo naa papo ko tete wa so bi bee ko ko gbe enu re dake laelae. Bi won ko ba tiri enikeni ko yoju ni won to le so awon mejeeji.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.