ORI-ORO-;ATUNYEWO AWON ISORI ORO : LSUS
OSE KINNI
ORI-ORO-;ATUNYEWO AWON ISORI ORO
-Oro-oruko
ORO AROPO ORUKO.
- Oriki
- Abuda oro aropo oruko
- Ate oro aropo oruko
- Irisi oro aropo oruko.
AKOONU
Oro aropo oruko ni a maa n lo dipo oro-oruko ninu apola oruko.apeere
‘Bolu je akara.
‘O je e.’
‘ewure je agbado Bola’
‘ewure je agbado re.
Abuda oro aropo oruko.
1. Oro aropo oruko ni eto to n toka si iye bi eyo tabi opo.apeere
O lo [ eyo ni o ]
Won wa [ opo ni.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.