Loading...

EDE YORUBA SSS1 SECOND TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

OSE KINNIORI-ORO-;ATUNYEWO AWON ISORI ORO -Oro-oruko ORO AROPO ORUKO. Oriki Abuda oro aropo oruko Ate oro aropo oruko Irisi oro aropo oruko.AKOONUOro aropo oruko ni a maa n lo dipo oro-oruko ninu apola oruko.apeere ‘Bolu je akara. ‘O je e.’ ‘ewure je agbado Bola’ ‘ewure je agbado re.Abuda oro aropo oruko.1. Oro aropo oruko ni eto to n toka si iye bi eyo tabi opo.apeere
OSE KEJIORI-ORO- AWON ISORI GBOLOHUN GEGE BI IHUN WON.Gbolohun-; ni ipede ti o kun to si ni ise ti on je.Won fun gbolohun ede Yoruba ni oruko gege bi ise ti o n se.Eyi ni awon gbolohun gege bi ihun won; Gbolohun eleyo oro-ise Gbolohun olopo-oro-ise Gbolohun alakanpoGbólóhùn eleyo oro-ise-: ni gbolohun ti o maa n ni eyo oro ise kan
OSE KETAORI-ORO-;AWON ISORI GBOLOHUN EDE YORUBA GEGE BI ISE WON. Ori-oro Isori gbolohun gege bi ihun wonOri – oro Isorí gbólóhùn gégé bíi ìse wọnOríkìÌsorí gbólóhùn pèlú àpẹẹrẹàkóónúGbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé.Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún.A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí won ń seÀpẹẹrẹBólú je èbèBàbá kọ ebèÈyà gbólóhùnOrisiirisii ni awon eya gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba.
OSE KERINORI-ORO-;AROKO ALAPEJUWEAroko alapejuwe-; je aroko ti a fi n se apejuwe nnkan,nnkan yii le je ohun elemii tabi ohun alailemii.Aroko alapejuwe ni a maa n lo lati yaworan nnkan ti o wa ni ookan aya eni sile ni ona ti eni ti ko si nibe yoo le fi oju inu wo o bi isele tabi nnkan naa se ri gan-an. Eyi ni apeere awon ori-oro ti o je mo aroko alapejuwe Aafin oba kan ti mo wo ri Oja ale Ija kan ti o soju mi Omobinrin kan ti o wu mi lati fe. Oja igbalode kan ti mo mo.
OSE KARUN-UNORI-ORO-;Aayan Ogbufo AKOONUAayan ogbufo ni ise titumo ede kan si ede miiranKi ogbufo to le kogo ja ninu itumo ede, o gbodo mo tifun tedo ede Geesi , ki o si le tusu ede Yoruba naa de isale ikoko.Kii se gbogbo oro inu ede kan naa le tumo si ode miiran.A ko gbodo mu gbolohun ni okookan lati tumo, sise bee yoo so ewa ati itumo iru ayoka bee nii.
OSE KEFAORI-ORO-;SISE AYOKA EDE GEESI SI EDE YORUBA ASA ORI-ORO-; IGBEYAWO ODE-ONI IGBEYAWO SOOSI IGBEYAWO MOSOLASI IGBEYAWO KOOTULode oni, aye ti di amulumala. Orisirisi ona ni a n gba gbe iyawo. A n gbe iyawo ni ile Olorun, a n gbe e ni kootu, a si n gbe ni mosalasi. Igbeyawo soosi yii fese mule laarin awon onigbagbo, igbeyawo mosalasi si mule laarin awon musulumi.
OSE KEJEORI-ORO-;ONKA YORUBA OOKAN DE EGBAA ONA MEJI PATAKI NI ONKA YORUBA PIN SINONKAYE (ON – KA – IYE)ONKAPO (ON – KA – IPO)‘m’ ni a fi n da pupo ninu awon onkaye Yoruba mo nigba ti a n fi (i) mo onkapoApeereONKAYE ONKAPOMeni (mu eni) = 1 Ikini (iko eni) = 1stMeji (mu eji) = 2 Ikeji (iko eji) = 2nd
OSE KESAN-ANOri-oro-; Aroko oniroyinAkoonu:Aroko oniroyin:- je mo iroyin sise tabi itan isle ti o ti koja seyin ti o si se oju eni ti a n royin re ni sise-n-tele ninu aroko oniroyin fun elomiran ti ko si nibe. A rii wi pe o fi ara pe aroko asapejuwe.Ki a to le se iroyin yori, a gbodo je eni ti o ni ife si gbigbo tabi kika iwe itan kekere.Eyi ni apeere ori-or, to je mo aroko oniroyin.Iroyin ipade maje – o – baje kan ti mo lo.Ayeye odun eyo ni ilu ekoOjo buruku, esu gbomi mu.Ipolongo eto idibo ti o koja
OSE KEWAAORI-ORO-;ISORI ORO-ORUKOAKOONU- oriki- orisiirisii oro oruko.- ise ti oro oruko n se ninu gbolohun.- lilo oro oruko ninu gbolohun. Oro –oruko ni awon oro ti won le da duro nipo oluwa,abo tabi eyan ninu gbolohun.AP. Baba ko ebe. Tolu fo aso. Mama se isu ewura.EYA ORO ORUKO. ORUKO ENIYAN : -Oro oruko le je oruko eniyan,eyi ni oruko ti o n toka si ohun ti o je eniyan.Ap

Subject Reviews:

Average Rating0
    0 Ratings
    Details
    5 Stars0%0
    4 Stars0%0
    3 Stars0%0
    2 Stars0%0
    1 Stars0%0

    No reviews yet.

    Also available in Bundles