AWON ISORI GBOLOHUN YORUBA GEGE BI ISE WON.. : LSUS
OSE KESAN-AN
AWON ISORI GBOLOHUN YORUBA GEGE BI ISE WON.
Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí won ń se. Àpẹẹrẹ:
Bólú je èbà
Bàbá kọ ebè
Èyà gbólóhùn. Orisiirisii ni awon eya gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba.
Gbólóhùn Eleyo oro-ise
Gbólóhùn Olopo oro-ise
Gbólóhùn Ibeere
Gbólóhùn Ase
Gbólóhùn Alaye
Gbólóhùn Akiyesi alatenumo
Gbólóhùn Kan
Gbólóhùn lyisodi
Gbólóhùn Asodoruko
Gbólóhùn Eleyo Oro-Ise-: ni gbolohun ti o maa n ni eyo oro ise kan
Apola oro oruko ati apola.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.