ISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISE : LSUS

OSE KERIN

ISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISE

Ko si bi eniyan se le wa ti ko ni se amulo gbohun bi ti wule ki o ri, eeyan gbodo se amulo gbolohun ayafi ti eniyan ba je odi loku. Ki ni gbolohun (sentence)?  Gbolohun ni ipede ti o kun, ti o ni itumo, ti o si ni ise ti o n je. Gbolohun ni a fi maa n se agbekale ero okan wa kale. Ara orisii gbolohun ni gbolohn olopo oro ise wa. Gbolohun olopo oro ni gbolohun ti o maa n ni ju eyo oro ise kan lo. Gbolohun yii maa n ni oro ise bi meji, meta, merin tabi ju bee lo. Apeere:

Kunle tete lo pon omi wa.

Ade sare gbe igi wa.

Mo wo o mo si ri.

IGBELEWON

Ki ni gbolohun Olopo Oro Ise?

IWE AKATILEWA

Ayo Bamgbose (1990) Fonoloji ati Girama Yoruba.... View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.