ORO – APONLE : LSUS
OSE KEFA
ORO – APONLE
AKOONU
Oro-Aponle je oro ti o maa n pon oro-ise ninu gbolohun. O maa n se afikun itumo fun apola-ise, ti yoo si je ki itumo re si tubo ye ni yekeyeke.
Tobi jeun die
Bolu n rin kanmokanmo bo.
Irufe oro-aponle inu ede Yoruba pin si orisii meji. Awon naa ni:-
Awon oro-aponle aiseda.
Awon oro-aponle aseda.
1 ORO APONLE AISEDA ni oro-aponle ti a ko seda. Iru oro yii kii ni ju silebu kan tabi meji lo. Awon ni fio, kia, gan-an logan.
O lo logan.
Ile naa ga fio.
2. ORO-APONLE ASEDA:- ni oro-aponle ti a seda lati ara oro-aponle nipa sise apetunpe oro-aponle.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.