Loading...

EDE YORUBA SSS2 FIRST TERM

Subject Scheme & Timeline:

Please check through the topics down and be sure it conform with the scheme you are using.

OSE KINNIANKOO ATI IJEYOPO FAWELIAKOONUAnkoo faweli ni ibasepo ti o n waye laarin awon iro faweli. Oun naa ni a mo si ijeyopo faweli.Faweli airanmupe le ba faweli airanmupe ko ankoo bee ni faweli airanmupe le ba faweli aranmupe ko ankoo.Ninu oro onisilebu meji ni a ti maa n toka si ankoo faweli.
OSE KEJIORO – AYALOAKOONUOro – Ayalo: ni awon oro ajeji ti a maa n ya wonu ede Yoruba lati inu ede miiran tabi ki a so wipe Oro ayalo ni mimu oro lati inu ede kan wo inu ede miiran lona ti pipe ati lilo re yoo fi wa ni ibamu pelu ede ti a mu-un wo. Oro – ayalo maa n mu ki ede dagba. Bakan naa, o maa n je ki oruko wa fun awon nnkan ati ero tuntun ti o ba n sese n wo awujo waYoruba ni ilana meji ti won n gba ya oro wo inu ede Yoruba, awon naa ni- Ilana afetiya- Ilana afojuyaILANA AFETIYA: Eyi ni pipe oro ayalo ni ona to sunmo bi awon elede se n pe oro gan-an:Bible - BaibuPeter - PitaTable - TebuEsther - Esita
OSE KETAAPOLA – ORUKOAKOONUAPOLA ORUKO:- Ni oro tabi akojopo oro to le duro gege bi Oluwa, abo pelu eyan tabi laisi eyan ninu gbolohun. Apeere:Ile woO waAwa naa je eba metameta.IHUN APOLA ORUKOApola – oruko le je eyikeyii ninu awon wonyiOro-oruko kan soso pereOro aropo-orukoOro aropo-afarajorukoOro – oruko pelu eyan
OSE KERINISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISEKo si bi eniyan se le wa ti ko ni se amulo gbohun bi ti wule ki o ri, eeyan gbodo se amulo gbolohun ayafi ti eniyan ba je odi loku. Ki ni gbolohun (sentence)? Gbolohun ni ipede ti o kun, ti o ni itumo, ti o si ni ise ti o n je. Gbolohun ni a fi maa n se agbekale ero okan wa kale. Ara orisii gbolohun ni gbolohn olopo oro ise wa. Gbolohun olopo oro ni gbolohun ti o maa n ni ju eyo oro ise kan lo. Gbolohun yii maa n ni oro ise bi meji, meta, merin tabi ju bee lo. Apeere:Kunle tete lo pon omi wa.Ade sare gbe igi wa.Mo wo o mo si ri.
OSE KERINISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISEAKOONUGbolohun Olopo Oro- ise ni gbolohun ti o maa n ni ju oro-ise kan lo, o le je meji meta tabi ju bee lo. Gbolohun olopo oro-ise naa ni a mo si gbolohun onibo. Apeere:Mo jeun mo si yo.Won wo aso, won si wo bata.Won n rin, won n yan, won si n se oge.ORISIIRISII GBOLOHUN OLOPO ORO-ISEGbolohun olopo oro-ise alakanpoGbolohun olopo oro-ise afibo
OSE KARUN-UNAWE GBOLOHUN EDE YORUBA.Oriki Olori Awe Gbolohun (Isori Awe Gbolohun) Awe Gbolohun Afarahe Orisii Awe Gbolohun Afarahe.AKOONUAwe gbolohun je ipede to ni oluwa ati ohun ti oluwa se (oro-ise). O je ipede ti ko ni ju apola-oruko ati apola-ise kookan lo. Apeere:Femi waSola sun.
OSE KEFAORO – APONLEAKOONUOro-Aponle je oro ti o maa n pon oro-ise ninu gbolohun. O maa n se afikun itumo fun apola-ise, ti yoo si je ki itumo re si tubo ye ni yekeyeke.Tobi jeun dieBolu n rin kanmokanmo bo.Irufe oro-aponle inu ede Yoruba pin si orisii meji. Awon naa ni:- Awon oro-aponle aiseda. Awon oro-aponle aseda.
OSE KEJEORO-AGBASOAKOONUOro agbaso:- je siso oro ti a gbo lenu oloro fun elomiran. Iru oro tabi iroyin bee gbodo je eyi to ti koja. Oro agbaso le je ohun ti enikan so nipa wa tabi elomiran. O si le je iroyin ohun to sele nibikan. Oro agbaso naa ni a mo si afo agbaran. Awon wunren atoka oro agbaso ni: so, wi, ni, ki, pase, wi pe, salaye, so fun abblTunde ni oun ko ni wa si ipade.Sola beere boya a ti jeunBi a ba n se agbaso, ayipada maa n de ba oro aropo oruko tabi oro aropo afarajoruko, ti eni to n soro ba lo oro aropo-oruko tabi oro aropo-afarajoruko enikinni ninu oro re – oro aropo –oruko tabi afarajoruko eniketa ni eni to n se agbaso yoo lo. Ap
OSE KEJOIPAROJE/IPAROJEAKOONUIparoje: ni fifo awon iro tabi siso awon iro nu nigba ti a ba n yara soro. Ti a ba n yara soro, a maa n pa awon iro kan je, awon iro ti a maa n paje ni: Iro konsonanti Faweli ati ohun Apapo konsonanti, fawli ati ohun ninu oroNibi ti a ba ti pa iro je, alafo yoo wa nibe, a o wa pa iro mejeeji po di eyokan. Pipapo apa oro eyo kan ni a mo si isunki.
OSE KESAN-ANAWON ISORI GBOLOHUN YORUBA GEGE BI ISE WON.Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí won ń se. Àpẹẹrẹ:Bólú je èbàBàbá kọ ebèÈyà gbólóhùn. Orisiirisii ni awon eya gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba.Gbólóhùn Eleyo oro-ise Gbólóhùn Olopo oro-ise Gbólóhùn IbeereGbólóhùn Ase
OSE KEWAALETA KIKOAKOONUOrisii leta meji lo wa ninu ede Yoruba, awon naa ni; - Leta gbefe ati Leta aigbagbefe.Leta mejeeji ni o ni eto ati ilana ti a n gba ko won.LETA GBEFE: ni leta ti a ko si obi, ara, ore, ebi, egbon, aburo tabi si eni ti a mo ri. Ilana leta gbefe ni: kiko adiresi eni ti o ko leta eyi le je olooro tabi elebe. Ni owo otun oke leta ni o maa n wa. Deeti Ibere leta pelu ikini ibere. Apeere: Tunji mi tooto, Aunti mi, Baba mi owon, Mama mi owon. Ikini ni o maa n bere leta. A le wi pe ‘Se alaafia ni o wa ati gbogbo ara ile. Inu Leta.

Subject Reviews:

Average Rating0
    0 Ratings
    Details
    5 Stars0%0
    4 Stars0%0
    3 Stars0%0
    2 Stars0%0
    1 Stars0%0

    No reviews yet.

    Also available in Bundles