AKAYE, : LSUS
OSE KEFA
AKAYE
akaye ni ohun ti a ka ti o si ye wa yekeyeke. Ti a ba fe dahun ibeere ti o tele akaye, a gbodo fi ara bale daadaa ka akaye, a gbodo ka akaye ni eemeji. Leyin eyi ni o wo awon ibi ti ibeere ti jeyo ninu akaye. Leyi ni yoo dahun ibeere. Ti o ba ti dahun ibeere tan ni yoo tun wo boya idahun ba ibeere mu.
Ka ayoka isale yii ki o si dahun ibeere ti o tele e.
Owo se pataki, o se koko. Bi o tile je pe owo ko fe ki enikeni damoran kanakan leyin
ohun, sibe a gbodo mo pe iranse lo je. Ko ye ki o di oga fun enikeni, ti Oba oke ba fi se buruji fun. Laye atijo, bi enikan ba sise to lowo laarin ebi, gbogbo ebi ni yoo janfaani re. Imo won ni pe owo ko niran, ko je ki won di agberaga. Bi awon baba wa se ni.... View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.