AROSO ALAPEJUWE : LSUS

OSE KEJI

AROSO ALAPEJUWE

AKOONU:                                                                 

  • Itumo.
  • Apeere.

Aroso ni ohun ti a ro lati inu arojinle wa ti a fe ko sile.  Orisiirisii aroso lo wa, a ni aroko oniroyin, onileta, alalaye, onisorogbesi, alapejuwe, alariyanjiyan.

 

AROSO ALAPEJUWE

Eyi je mo sise apejuwe eniyan, ibikan tabi ohun kan lona ti o se pekipeki nnkan naa. Tori a le so wi pe aroso alapejuwe ni aroso ti a fi n se apejuwe eniyan tabi ibi kan(Descriptive essay).  Apejuwe wa gbodo fi han pe a mo ohun ti a n soro nipa re.  Apeere ori oro aroko alapejuwe ni:-

  • Ile baba mi
  • Oja ilu mi
  • Ore mi ti mo feran ju
  • Ile iwe mi

ILANA AROKO.... View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.