AROKO ALAPEJUWE . : LSUS

OSE KETA.

AROKO ALAPEJUWE

AKOONU:                                                               

  • Itumo.
  • Apeere.

Aroko ni ohun ti a ko sile lati inu arojinle wa fun elomiran lati ka a.  Orisiirisii aroko lo wa, a ni aroko oniroyin, onileta, alalaye, onisorogbesi, alapejuwe, alariyanjiyan.


AROKO ALAPEJUWE

Eyi je mo sise apejuwe eniyan, ibikan tabi ohun kan lona ti o se pekipeki nnkan naa. Tori a le so wi pe aroko alapejuwe ni aroko ti a fi n se apejuwe eniyan tabi ibi kan(Descriptive essay).  Apejuwe wa gbodo fi han pe a mo ohun ti a n soro nipa re.  Apeere ori oro aroko alapejuwe ni:-

  • Ile baba mi
  • Oja ilu mi
  • Ore mi ti bimo feran ju
  • Ile iwe mi

ILANA AROKO (ILE.... View More

Subscribe now to gain full access to this lesson note

Take Me There

Click here to gain access to the full notes.