AROKO ASOTAN/ONIROYIN, : LSUS
OSE KARUN-UN
AROKO ASOTAN/ONIROYIN
AKOONU:
- Itumo
- Apeere.
- Igbese.
Aroko ni ohun ti a ko sile lati inu arojinle wa fun elomiran lati ka a. Orisiirisii aroko lo wa, a ni aroko oniroyin, onileta, alalaye, onisorogbesi, alapejuwe, alariyanjiyan.
Aroko oniroyin: ni a n pe ni aroko asotan. Iru aroko yii ni a ti maa n so itan isele ti a fi oju ri tabi eyi ti a kopa ninu re, tabi ti a gbo lati enu enikan. Aroko yii maa n so nipa ohun to ti sele seyin ni. Die ninu awon ori oro ti a le ko aroko oniroyin le lori ni wonyi:-
- Ija igboro kan to soju mi
- Ijamba moto kan ti mo wa ninu re
- Ojo kan ti a ko le gbagbe
View More
Subscribe now to gain full access to this lesson note
Take Me ThereClick here to gain access to the full notes.